Sunday Akin Dare, Date of Birth

    

Sunday Akin Dare

Date of Birth: 29-May-1966

Zodiac Sign: Gemini


Show Famous Birthdays Today, World

👉 Worldwide Celebrity Birthdays Today

About Sunday Akin Dare

  • Sunday Akin Dare ti a bi ni ojo kokandinlognon, Osu Kaarun odun 1966 je ogbontarigi oniwee-iroyin omo Naijiria ti o tI sise ni opolopo ile-ise iwe-iroyin.
  • O ti sise ni oniruuru ile-ise agbohunsafefe telifisonnu, redio ati ile-ise atewe-iroyin, o sin ni imo to dangajia fun odidi odun meeedogbon gbako ninu ise yii.
  • O ti fi Igba kan je He was the komisanna-agba ti Nigerian Communications Commission (NCC), Aare ( President of the Federal Republic of Nigeria Muhammadu Buhari ni o yan-an si IPO naa ni Osu ikejo odun 2016.
  • Lowolowo bayii, o je Minisita fun eto nipa odo ati ere-idaraya ti orile-ede Naijiria.
  • Aare Buhari yan-an si ipo minisita ni ojo kokanlegun, Osu keejo, odun 2019.
  • O je omobibi ipinle Oyo

Read more at Wikipedia